I
This Odu emphasizes the importance of resilience and strength.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Irosun abeyin kanran kanran
Adifa fun oletapa
Eyi ti nse omokunrin ogodo
Nijo ti ori ogodo gba obi mefa
Nitori omo titun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ni kobo ori re pelu obi kire ole ba to lowo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Irosun keyinda awo akin oyin
Adifa fun akin oyin
Igba ti n fomi oju so gbere omo bibi surusun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire fun eni toda ifa yi ifa sope kiwon o kiesi alaboyu kan nibeyen oyun towa ninure ki won o rubo fun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewure ni wom yoo fi paro omo to febi
Opolopo eyele
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Eesun lote koko janan
Oun reti apon riri gangan
Adifafun atoye bi tiise omoyeye ega
Ti n nira kaka alaile dide
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa loun pere fun eni toda ifayi ilorubo nitori arun oju ifani toba pe saa oju eleyi yo mo pon korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko die
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kanle kanle aran
Adifa fun opa
Ti yoo pejo ti o poro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa e ki eleyi o rubo isegun ota pe enikan niyi to geju eleyi lo tin ba sota korubo kole ba segun re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe esisi merindinlogun aolo pomo iyere merindinlogun ao fi se eja abori kanje leponiyo ao se tiyo jina to ba tijina ao wa se adura si ni ihoho aoje ni ihoho
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Eso eyinolobe ewe rerinkomin odidi kan a o jopo ao fi sin gbere kan ni arin ori
Explore Ifa
Irosun Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Okanran Odu.
