I
This Odu signifies the importance of wisdom and foresight in overcoming challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Aru pakiti ni se bi oku wolu
Laba laba ni se bi esun jako
Adifafun ifakolade
Ti n se elemoso awo
Eyi to ko isin ope sile
To loun o roju sin ifa mo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Owo mi ewa
Ese mi ewa
Apari mi o si kokanlelogun
Adifafun ijilamere
Abufun iji laa mere
Won o mo ke gbami gbami
Nitori ogun omo araye
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ata para
Ati piri
Adifafun sekere
Tii se omo olakole
Igba ti n momi oju sogbere aje
Explore Ifa
Irosun Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Oyeku, Irosun Iwori, Irosun Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Ogbe Odu.
