Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Irosun Oturupon

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of introspection and self-discovery.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/irosun-oturupon
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Pansa ojugun han Obara dudu palapala AdifafunOrunmilaWon ni baba o rubo Koju re o le baa kan bi pansa Ojugun naa obara dudu palapala Adifafun OmoeniyanWon ni won o rubo koju won o le ba kanOrunmilanikan ni n be leyin ti n rubo Orunmila lo bijokun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oju ire gbogbo n pon eleyii, pe ko rubo, ifa ni oun ti eleyii dafa si da, ko rubo ko le ba dero, ko lo bo esu ni akuko adie Ifa pe ki eleyii o rubo ija igbona, ko si rubo laiku arare pe yoo si rire Ifa pere fun eni to dafa yii, ko rubo, ifa ni eleyii lo ree peogunloun ba oun ja ati osa egun kankan, pe awon kan n be legbe re ti yoo fe maa ba nkan ini re je, pe ebo ni ko ru Ifa loun pere omo fun eleyi keleyi ko mo je iru nitori abiku

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Opolopo owo AkukoEyeleOpolopo owo Akuko adie Opolopo owo Eku eja Abo adie Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kada ni tutu Ka te ni tutu AdifafunOrunmilaWon ni baba o rubo Ki inu ile re ko ma baa se gbona

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pere isegun fun eleyi kosimo gbokanleagbarakeleyi ko lo re boo gun pelusangoko rubo nitori elenini

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akukodie Opolopoowo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ope pansere kanle Adifafun Onimoba iko Igba ti n je nirangun ota Keke ni di won oku Apata ni di won oja Nijo eni baku Omo eni lorisa fidin won lede ni Adifa fun awo tunde Tii se elemoso awo lode orunwa Eyi toko isin ope To loun ose tifa mo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifa yi ko rubo ifa ni oju pon eleyi owa ni oun ko se tifa mo ko ma se be oifda ni ko gbebo fi oun sile komo sebi toun Ifa pere fun eni toda ifayi Ifa ni gbogbo oun toba tifeje ko mo fowo ko toje nitoriarunifa ni oun ko nije ki o se ojojo ko si ni towo eeri bonu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

EyeleAkuko Opolopo owo AkukoEyeleOpolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ajilowo awo won lode ilowo Ajiloro awo won lode iloro Moriwo olee ni sawo lode ilomo AdifafunorunmilaOju ti n pon ikin latesin Ope ori okiti abagolo sele Adifa funorunmilaIfa n raye alainiku Ota ridiridi awo ile kelekun Adifa fun kelekun Eyi to lohun ninu Ti n begun tin borisa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda fayi korubo ifa ni obinrin kan ni yen to ni oyun komo bawon buogunati orisa tori ki ojo ikunle re ko mo ba nira Ifa pere fun eni todafayi ifa ni awon kan wa bi pe ko le la mo laye korubko si fi eko bo fa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abo adie Opolopo owoEyeleAkuko Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

(WEALTH) MEDICINA Dos Palomas, Dos ratas emon, hierbas emo, el emon agbo Rata se quemara todo junto y se verteran vino y uno lo tomara con Eko frio todas las mañanas (VICTORY) MEDICINA La raiz del palo atori se triturara y se usara para cocinar caracoles con aceite de palma y sal y despues de la coccion la persona lo comera cuando se enfrie. IROSUN ATERE ESE IFA Ajilowo awo won lode ilowo Ajiloro awo won lode iloro Moriwo olee ni sawo lode ilomo AdifafunorunmilaOju ti n pon ikin latesin Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe o rubo Won ni ki baba o fi isueyelerubo Nje oju ti n pon ikin latesin nko Oungo isu ko sai ko ire gbogbo de poro poro Aje n wa mi bo wa o Apa otun, apa osi leyele fii ko re wole Tomi wa ara gbogbo ni sefun sefun fi n sefun aje Ire ti n wa mi bowa koni dabo atare ki di tire laabo Ifa ni oju aje lon pon eleyi korubo ki iponju re le deroEyelemerindilogun (16) Isu Opolopo owo Ewe esisi ao fi oti rega onike gbo dada ao lo igbo ti yo kunan loto ao lo egun ori gbi gbe loto ao wa damejeji si oun ti a gbo yi ai gbe mun ao se ki a tomun ojo kan nan ni ao fi mu kogbodo di ojo keji o

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ibepe ti kop on eyo kan o be epo arare kuro a o wa be kekeke sinu igo fun ge keke ke sinu igo funfun ao roomi tutusi toba di ojo keta ni o toni gass kookan

Videos

Watch Irosun Oturupon teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Irosun Meji,Irosun Ogbe,Irosun Oyeku,Irosun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Oturupon Odu.