I
This Odu highlights the need for courage and determination.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Okiti pete pete pete owo eluju
Adifafun agan oribi
Ti n sunkun airibi
Ti n gbaye alairipon
Ti n fowo osun nu ogiri gbigbe
Oromo leyin adire obu puru sekun o leye oko se bimo juni lo Olu ikunfin aboyun
Oun sunkun poun kobi tibi tire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ika loun pere omo fun eleyi korubo kolebabimo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku eja abodie
Eyele
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Aherepe ina nijole
Adifa fun aye
Ti n fomi oju segbere omo bibi surusu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa sope kin won o mo fi oro kun ogun yan ra won je ifa ni eleyi ko fi aso kun ebo rupelu fila to baje obinrin ni yoo fi ewure pelu gele ebo ru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Aso
Fila
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Atapata kiti ponpon
Adifa fun eda ori okiti
Igba ti je ni rangu ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa loun pere fun eni to da ifayi korubo ifa ni arin ota eleyi wa ifa ni awon ota repo sugbon oun ni yoo segun kofi oka ati ada ku eba
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
Oko
Ada
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Igba nla abeku digi
Adifa fun ori
Ti n momi oju sogbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni todafa yi ko rubo ki ire ba le te lowo ifa ni oju ire gbogbo nipon eleyi ko sirubo fun omo re kan ko mo ba soun ifa ni omo kan nbe nib eyen toni agidi ki won o rubo fun ki agidi yen mon ba pa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Akuko
Eye etu
Opa aso funfun mefa
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Egbo tannaposo ao lo po mo iyere ao fi se eran elede ti a ge si merindinlogun (16) leponiyo ti o ba jinnaan ao se adua si ao ko je
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Egbo odun pupo egbo atori pupo odidi atare kana o jo po ao o ma fi fo eko tutu mu larolaro
Explore Ifa
Irosun Ogunda is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Ogunda Odu.
